9ice – Olodumare (Lyrics)
Olodumare Song Lyrics By 9ice

Eminent Nigerian musician and dancer, 9ice has released the lyrics to his new song “Olodumare.” This release marks his return to the music scene.
The words in “Olodumare” carry deep meaning and can capture your attention the moment you start reading or listening. It’s a masterpiece that fits perfectly for anyone who enjoys top-notch music.
Now that the lyrics are out, you can sing along with 9ice and enjoy the song.
Olodumare Song Lyrics By 9ice Below.
Ệmí kan, ẹdá kan
Ayé kan ló wà
Ệmí kan, ệdá kan
Ayé kan ló wà
Ah ah
Tí n bá ń lọ lonà màá ko ire
Àbọ̀ mi ma ń da ire
Gbogbo ìrìn tí mo bá ń rìn ma ń dʼoore
Gbogbo ișe tí mo bá ń ṣe ló ma ń dʼọpẹ́
Tí n bá ń bộ ní ibìkan
Tí n lọ sí ibìkan
Màá gba ire
Tí mo yà sí ibì kan ma gbʼọp
Ònà mi ma ń fọ ire
Olódùmarè ló jẹ́ kó rí bẹ́ẹ̀
Șe ni mo ya ma ń dákẹ́ ṣʼọpẹ́
(Olódùmarè olórí)
(Olódùmarè adarí)
(Olódùmarè mare)
(Olódùmarè marè)
Șèbí ìwọ ni adákjà bí idán
Ajàbí-èpè bí àrá o
(Bàbá bàbá ah)
Șe mí lóore àșepé
(Sàánú ọmọ ò rẹ)
Bàbá mi
(Bàbá bàbá ah)
Má dáwo oore è rẹ dúró
(Șàánú ọmọʼộ rẹ)
Ìyà ò lè jẹ mí torí mi ò p’awo dà
Ọkanlọmọ (Anaconda)
Colour media
(Cosatira)
Hallelujah
(Wộn á rí wonder)
Mo ní Badmus onà wa á là
Tí n bá ń lọ lộnà màá ko ire
Àbò mi ma ń da ire
Gbogbo ìrìn tí mo bá ń rìn ma ń dʼoore
Gbogbo ișẹ́ tí mo bá ń ṣe ló ma ń dʼọpẹ́
Tí n bá ń bộ ní ibìkan
Tí n lọ sí ibìkan
Màá gba ire
Tí mo yà sí ibì kan ma gbʼọpẹ
Ọnà mi ma ń fọ ire
(Olódùmarè ló jẹ́ kó rí bẹ́ẹ̀)
Șe ni mo ya ma ń dákẹ ṣʼọpẹ́
(Olódùmarè olórí)
(Olódùmarè adarí)
(Olódùmarè marè)
(Olódùmarè marè)
Șèbí ìwọ ni adákéjà bí idán
Bí i Ogbèríkúsá
It’s just by the way
Bí Ọlorun ní bẹệ
E ò le bá mi șa it’s just by His Grace
I shall never fall
Ìyà ò lè jẹ mí torí mi ò p’awo dà
Ọkanlọmọ (Anaconda)
Colour media
(Cosatira)
Hallelujah
(Wộn á rí wonder)
(Wộn á rí wonder)
Mo ní Badmus ộnà wa á là
(Șe mí lóore àșepé)
(Șe mí lóore àșepé)
(Sàánú ọmọ ọ̀ rẹ)
Șe mí lóore àșepé
(Șe mí lóore àșepé)
Șàánú ọmọ ọ̀ rẹ
Șe mí lóore àșepé)
(Șe mí lóore àșepé)
Șàánú ọmọ ọ̀ rẹ
It’s Bizzle on the mix
Do you find Tunesloaded useful? Click here to give us five stars rating!